1 / 5

GIRAMA

GIRAMA. GBOLOHUN EDE YORUBA. KIN NI GBOLOHUN?. Gbolohun ni ipede ti o kun ti o ni oro-ise ti o si ni ise ti o n je. Gbolohun gbodo bere pelu leta nla , ki o si pari pelu ami idanuduro . Ona meji ni a le pin gbolohun si : 1. Ilana ihun 2. Ilana ilo.

Télécharger la présentation

GIRAMA

An Image/Link below is provided (as is) to download presentation Download Policy: Content on the Website is provided to you AS IS for your information and personal use and may not be sold / licensed / shared on other websites without getting consent from its author. Content is provided to you AS IS for your information and personal use only. Download presentation by click this link. While downloading, if for some reason you are not able to download a presentation, the publisher may have deleted the file from their server. During download, if you can't get a presentation, the file might be deleted by the publisher.

E N D

Presentation Transcript


  1. GIRAMA GBOLOHUN EDE YORUBA

  2. KIN NI GBOLOHUN? • Gbolohunniipedeti o kun ti o nioro-iseti o siniiseti o n je. • Gbolohungbodoberepeluletanla, ki o siparipeluamiidanuduro. • Onamejini a le pin gbolohunsi: • 1. Ilanaihun • 2. Ilanailo

  3. IPINSOWOO GBOLOHUN NIPA IHUN • Awongbolohunabeihunni: • 1. GbolohunAlabode • 2. Gbolohunonibo • 3. GbolohunAlakanpo • 1. GBOLOHUN ALABODE: • Eyinigbolohunti a tun mo sigbolohunkukurutabigbolohuneleyooro-ise. • Apeere: Sade je isu.

  4. Apeja pa ejaaro. • 2. GBOLOHUN ONIBO: Eyiniinugbolohunti a tifigbolohunkanboinugbolohunmiiran. • Apeere: • Efoti won ratigbo. • O darape mo wa. • 3. GBOLOHUN ALAKANPO: Inugbolohunyiini a tifioro-asopo so gbolohunmejipo.

  5. Apeere: • Mo lo sioja • N koriatara = Mo lo siojasugbon n koriata.

More Related